Adewale Ismail

Adewale Ismail Segun

20/04/2022
05/04/2022

Allah

24/03/2022

Enyin ore mi, e ku atijo o e ni nkan na sele ni mo ma ranti aiye atijo, nigbati nko ju kekere lo ti mo ma nba baba mi lo si oko wa lohun ni oke Egan wa nitori lati igbati mo ti wa ni kekere ni baba mi ti so mi si ile iwe sugbon nigbati a ba gba isimi ni ile iwe emi a ba oko wa lo akoko yi se pataki pupo ni igbesi aiye mi akoko igbadun patapata gba ni itan ti ng o so fun yin loni je itan nipa okunrin kan ti mo ba pade nigbana akoko didun ni oko wa nigbati a ba ko agbado tutu lu ina ti a nfi ehin ho agbado tutu je bi a ba je a ba je agbado tutu ni osan a ma je iyan lale iyan titobi Ori ewe ogede ti o ma nse inu wa bi apo ekuro mo si tun ranti dada pelu pe takute wa a ma pa eran awa a ma se alabapade igbin olu a si ma hu kakiri ninu oko wa.......

19/03/2022

God bless my family

22/08/2020

Address

Sabo Sagamu
Sagamu
ADE

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adewale Ismail posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share