13/04/2024
OJUSE Ml (3)
Oga awon oyinbo Niki obinrin yi loko iwe eri wa , (certificate) bayi ni obinrin gba ile lo lati loko certificate re wa , bi oyinbo seri iwe eri obinrin yi bayi lo Erin kkkkk ,bayi loni ki obinrin yi wasi ile ise awon, leyin ojo meta oko obinrin ti kose ojuse re ninu ile wa pelu awon ore re lojo kan nibi won ti nse faaji ,koto kuro nile lojo yen ni iyawo re beere owo lowo e ti o sini kosi owo kankan gbogbo nkan ti won ra nibi faaji yi okunrin yi losan owo gbogbo e , won pari faaji bayi ni awon agbofinro bade won ni gbogbo won wani ara awon afurasi bayi ni won ko gbogbo won losi ago olopa ti won si tiwon mole fun bi ojo meta .
Leyin to kuro ni atimole awon oga re nibi ise ni ki o lo duro sile naa fun igba die, gbogbo awon nkan ibi ise re ni won gba lowo re pelu motor ti won gbe fun , bayi lo di eniti koni ise kankan lowo mo ooo .
Obinrin yi loba awon oyinbo ni office won lojo ti won ni ki o wa , bayi ni wo so fun obinrin yipe ki o ki rare ku orire , won ni ki obinrin yi wa beere ise ,won gbe motor kan fun obinrin yi pelu opolopo owo bayi ni obinrin yi di eniti ko ta oja ate mo, ti o wa di eniti ori ise si office awon oyinbo,
Hmmmmm! OJUSE Ml ,kinwa lotun sele mo nbo Eyin temi.