DivineFavour-Enterprise

DivineFavour-Enterprise Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from DivineFavour-Enterprise, Shopping & retail, No 21 Ayegun Okeodan Apete, Ibadan.

Order for your ponmo ijebu at affordable price
Cut #200(25pieces) 4,500 (50pieces) 9k
(100pieces) 18k
Cut #500(25pieces) 11,250
(50pieces)22,500
Location Ibadan
Delivery to any state 💯

iranlowo oju ojo fun gbogbo oju Tori  post Yi🙏
29/10/2025

iranlowo oju ojo fun gbogbo oju Tori post Yi🙏

THE CEO HER SELF😊
29/10/2025

THE CEO HER SELF😊

14/03/2025

With Olori Temmy Omolara – I'm on a streak! I've been a top fan for 7 months in a row. 🎉

11/03/2025
LEHIN OṢÙ MẸJỌ....🥹Season 2: The surprise 🙆🏾‍♂️😳Mr Olaitan fẹ mọn irú èyán ti ohun nba gbélé. Lati igbati o ti fẹ Temito...
11/03/2025

LEHIN OṢÙ MẸJỌ....🥹

Season 2: The surprise 🙆🏾‍♂️😳
Mr Olaitan fẹ mọn irú èyán ti ohun nba gbélé. Lati igbati o ti fẹ Temitope. Ko fi ọjọ kan ronú ri pe ki ohun ti ę bere nkan to fa ìpínyà láàrin Temitope ati ọkọ rẹ 🥹. Sugbon loni yi , ero yẹn wa si lọkàn 🙆🏾‍♂️😳... Temitope ngbiyanju lati jẹ ki Mr Olaitan mu ẹnu kuro lori ọrọ yẹn, ṣùgbon Mr Olaitan ni afi dandan ki o sọ nkan to ṣẹlẹ fún ohun .😨😨
Hehee! Iná ti wa jo dori koko bayi o. Kilo fẹ ṣẹlẹ bayii?🙆🏾‍♂️🥹
Itan yii ṣi ntesiwaju....✍🏽
Ti ę ba fẹ máa rí àwọn itan yi ka ki ę follow page DivineFavour-EDivineFavour-Enterprise

O SEMI LAANU PÚPỌ 🙏🏽😭Báwo ni iya yi o ṣe máa sún òrun ayọ bayi , ti ọmọ bíbí rẹ kanṣoṣo yi o ma sùn inu ojo(rain) laijẹ ...
11/03/2025

O SEMI LAANU PÚPỌ 🙏🏽😭

Báwo ni iya yi o ṣe máa sún òrun ayọ bayi , ti ọmọ bíbí rẹ kanṣoṣo yi o ma sùn inu ojo(rain) laijẹ nkankan sún. Iru obi wo l'eyi !🤦🏽‍♂️💔
Itan yii ṣi ntesiwaju... Ẹ darapọ mọn wa lori page 👉 DivineFDivineFavour-Enterprisele ri awọn nkan ti yi o ṣẹlẹ 🥹

Address

No 21 Ayegun Okeodan Apete
Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when DivineFavour-Enterprise posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to DivineFavour-Enterprise:

Share