IRIRI LAGBA OGBON

IRIRI LAGBA OGBON Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from IRIRI LAGBA OGBON, Shopping & retail, ADESIYAN AREA MODAKEKE, Ife.

06/12/2023

Beni won si ni ogbo ologbon ni kii je ka pe agba ni were

11/11/2023
11/11/2023

ORIN David 24

11/11/2023

Ejowo gbogbo ile ebawa da si oro yi .enikan lo fi ejo iyawo e sun mi amon ko to di pe mo fun lesi mo fe kàdi jo gbe yewo,Oko iyawo yii ni.ni gbogbo igba ti iyawo oun ba ti danaa ni ale ni oma nso pe brother to wa ni apartment keji awon ko ni owo lowo lati fi jeun pe ko si ise lowo won mon pe enu iwon ba onje ti awon se pe awon ti gbe fun brother ye nibe pe ki oko oun ma binu ko manage iwon ba oun je ti oun gbe fun .amon oso fun mi pe oti wa di gbogbo igba.Egbo gbogbo ile ki ni ki oko obinrin yi se

Yoruba ni ogbon ologbon ni kii je ka pe agba ni were.lodo tiyin kini oun ti afe fi se ogbon .ti yio wulo fun emi ati eyi...
11/11/2023

Yoruba ni ogbon ologbon ni kii je ka pe agba ni were.lodo tiyin kini oun ti afe fi se ogbon .ti yio wulo fun emi ati eyin pelu awon ewe iwoyi

11/11/2023

Mo ki yin lokurin ati obinrin lo monde lagba .iba eyin to laye teledumare ko aye le lowo .keje ko ju wa se.gbogbo eyi ti aba wi ni yaara yi keledumare ko je ko di ogbon fun wa

Address

ADESIYAN AREA MODAKEKE
Ife

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when IRIRI LAGBA OGBON posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share