Toko lase

Toko lase Tokolase

01/05/2022

KI OLOWO JU OKORE LO KONI KI OMALE TERIBAFUN olorun tofi okunrin she olorile otimo kii atomo fun idi eyi obinrin teriba fun alase reee

20/02/2022

Oro ife dabi iji eniti ategunre bafesi niki ni yiomon ife

18/02/2022

Oro okunrin si obinrin oda gegebi oke si isale enikan oribire fun enikan aforiti ni koko

30/01/2022

Igbeyawo fun okunrin je igbe iyaawoo besi ni obinrin da gege bi omo irakoro tiojepe kolegbo oro ni owo kan ayafi tobafedi egba sungbon awa ni agbodo fi suru gbe be gele naa ni okunrin naa ni owo obinrin agbodo fi suru gbe ki ilewa maba daru olorun yioo ranwa lowo

24/01/2022
03/01/2022

Eyin obinrin ibiti ebakusi larin eyin ati oko yin epe si aakiyesi esu koniyayin amin

28/11/2021

Jeki okore mo ohuti ofe yatosi ohutofe sotito pelu oko re nitori ojowaju omore

30/09/2021

Olorun yiowa pelu gbogbo waooo amin

29/09/2021

Ti obari enitosope ohun okore se okunrin kankan kolebaohun dawo iro nioo eyi toju tie lohun dojuko rantipe aope lodo olorun otumosi okore kole petan

14/08/2021

Oko ni olori aya eyin obinrin emase ko oro si oko yin ni enu emagbo tokoyin

10/08/2021

Oko ni ade ori aya eyin obinrin eteriba fun oko yin

Address

Tokolase
Ibadan
5030

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Toko lase posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share